IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday 21 November 2018

ONI LOJOOBI TOYIN TIWA, E JE KA KI OMO AGBOLADE KU ORIIRE

A fi tayo-tayo ati idunnu ba eeyan wa pataki, ore wa to yaayi, Oluwatoyin Lizzy Agbolade, okan ninu awon akoroyin ileese Alariya Oodua ku oriire ayeye ojoobi e to waye loni-in . 

A gba a ladura fun Oluwatoyin pe ko se opo odun laye ninu ola, ola, owo, alaafia ara ati ifokanbale to peye. Wa a dagba, waa dogbo,waa se opolopo oriire laye. Igba odun iseju aaya ni fun Lizzy to sha proper, Oluwatooyin to sa prapra 

No comments:

Post a Comment

Adbox