IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday 21 November 2018

A BA EEYAN WA DAADAA, KUNLE BABARINDE, OLOOTU IWE IROYIN ALARIYA OODUA DARO IKU MAMA E, DEACONESS DEBORAH

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ba eeyan wa daadaa, Pasito Oyekunle Babarinde, Olootu Iwe Iroyin Alariya Oodua ati olukotan iwe 'Yoruba ni tooto', daro iku mama e, Deaconess Deborah Babarinde to jade laye loni-in.

Iku mama ba wa ninu  je pupo, sugbon gege bii olugbagbo ododo a gba ohun ti Olorun wi, adura wa ni pe ki Olorun te iya wa safefe ire, ko fori gbogbo ese won ji won, iwaju ti won doju ko ko  dara, eyin ti mama rere fi sile ko ma baje.

Olorun ko ni i se eyii lakufa ninu ebi Babarinde. O ka wa lara gan-
an.

No comments:

Post a Comment

Adbox