IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 7 October 2018

GONGO SO LOJO TI GBAJUMO OLORIN ISLAM, ALAAJA MONSURAT AKOBI-ESAN SAYEYE NLA



Yoo pe e daadaa ki gbajumo olorin Islam nni, Alaaja Monsurat Ajelero  Adegbemiro tawon eeyan tun mo si Akobi-Esan too gbagbe ojo Abameta, Satide to koja yii.

Ojo naa lobinrin olorin Islam to kawe-jade nileewe giga 'Lagos State University' sayeye onibeta lojo kan soso. Ayeye ohun to waye ninu gbongan ilejooba ibile Ado-Odo-Ota nifilole rekoodu e to pe ni 'Ta-n-tolohun', ifilole egbe awon ololufe e ati ifilole ajo alaaanu to fi n ran awon opo lowo ti waye.Aafaa agba oniwaasi agbaaye nni, Sheik Muyideen Ajani Bello lo se waasi lojo naa, baba naa lo ba Akobi Esan gbowo lowo awon alejo pataki ti won ba ko rekoodu e ohun jade. Alaaji Bashit Aponle Anobi lo koko dari eto yii, ko too di pe agba sorosoro nni, Oloye Abiodun Adeoye ti gbogbo aye mo si Afefe Oro dari eto naa to fi di ale patapata ti eto naa pari.

Bakan naa lajo to n ja fun eto awon obinrin lorile-ede yii fi ami-eye eni to n ran awon obinrin atawon to ku die kaato fun lowo.

Lara awon olorin Islam ti won korin nibe lojo naa, Efanjeliisi Friday Paul Omo Abule,

Hajia Sukurat Wazzy ti won tun n pe ni Akobi Ayeloyun, Alaaji Wasiu As-Sidik ti gbogbo aye mo si Baba-n-waka ati Alaaja Mistura Ashafa Aderohunmu.

 Bamubamu lawon eeyan ku inu gbongan yii, bawon olowo se wa nibe, bee lawon olola wa nibe, bee lawon oloselu ko gbeyin, ko si yo awon afenifere sile. Bakan naa ni won tun se iwosan ofe fawon eeyan
Aafaa agba oniwaasi agbaaye nni, Sheik Muyideen Ajani Bello lo se waasi lojo naa, baba naa lo ba Akobi Esan gbowo lowo awon alejo pataki ti won ba ko rekoodu e ohun jade. Alaaji Bashit Aponle Anobi lo koko dari eto yii, ko too di pe agba sorosoro nni, Oloye Abiodun Adeoye ti gbogbo aye mo si Afefe Oro dari eto naa to fi di ale patapata ti eto naa pari.


Bakan naa lajo to n ja fun eto awon obinrin lorile-ede yii fi ami-eye eni to n ran awon obinrin atawon to ku die kaato fun lowo.

Lara awon olorin Islam ti won korin nibe lojo naa, Hajia Sukurat Wazzy ti won tun n pe ni Akobi Ayeloyun, Alaaji Wasiu As-Sidik ti gbogbo aye mo si Baba-n-waka ati Alaaja Mistura Ashafa Aderohunmu.





































No comments:

Post a Comment

Adbox