Ibo ogorun-un meji ati meje ni Funke fi bori alatako e to ni ibo mejilelogbon. Ninu oro Funke lo ti dupe fun gbogbo awon omo egbe atawon asaaju egbe ti won fibo gbe e wole.
Pelu ohun to sele yii, Funke ni yoo koju awon ti egbe mi-in ba fa sile lati koju e ninu ibo gbogboogboo ti yoo waye
lodun to n bo.
No comments:
Post a Comment