IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 18 September 2018

OPE O: GBAJUMO OLORIN ISLAM, ALAAJI SHARAFFDEEN ALBSHRAH RA MOTO OLOWO NLA

Inu ayo ati idunnu ni gbajumo olorin Islam, to fi ilu Eko sebugbe, Alaaji Sharaffdeen Sulaiman tawon eeyan mo si Albushrah wa bayii. Ko si ohun to fa eyii ju moto olowo nla ti okunrin naa sese ra lo.

Ojutole gbo pe ni nnkan bii ose meloo kan ni Olorun soore nla yii fun irawo olorin omo bibi ilu Ilorin yii,Oko nla naa la  gbo pe Albushrah fi n jaye ori e bayii.

Gbogbo wa nileese OJUTOLE naa ba Albushrah dupe lowo Olorun fun oore ayo yii, Olorun yoo se eyii to ju tile yii lo



No comments:

Post a Comment

Adbox