IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 17 September 2018

ONI LOJOOBI SBLAIR, GBAJUMO PRODUSA AWON OLORIN

A ba eeyan wa ati ore wa, Sola Abbey ti gbogbo aye mo si Sblair,  ku oriire ojoobi e to waye loni-in. Gbogbo wa pata la ba gbajumo ati ogbontarigi produsa awon olorin ku ayeye ojoobi e yii.

Ki Olorun je ki Sblair pe laye, ki Eleyinjuege Baba Hesphiba sopo odun
laye ninu ola, owo ati alaafia ara. Igba odun, iseju aaya ni.  

No comments:

Post a Comment

Adbox