IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 9 September 2018

O MA SE O:SOJI ADETOKUN, GBAJUMO SOROSORO TI KU O

Iroyin ibanuje to kan wa lara lati odo awon sorosoro ori radio ni pe, okan ninu won, Soji Adetokun, ti jade laye. Anaa, ojo Aiku, Sannde niku mu okunrin naa lo.

Okan ninu awon osise ileese radio Bond FM lokunrin yii, eto kan to maa n waye ni gbogbo Ojobo, Tosde toruko e n je 'Ka-jo-se-e'

lokunrin naa maa n se.

Ki Olorun fori ji i, ko duro ti awon ebi to fi sile.

No comments:

Post a Comment

Adbox