Titi dasiko yii lawon ololufe orin Islam, niluu Dublin, si n soro nipa ikojade rekoodu tuntun ti gbajumo olorin Islam, omo orile-ede yii, to fi ilu Ireland, sebugbe, Alaaja Rodiat Ayinke Sanni Adeboye tawon eeyan tun mo si Hello Olohun se. Rekoodu tuntun naa to pe ni 'Alahu ni' lawon eeyan ba a ko jade lojo yii .
Bamubamu lawon eeyan kun gbongan nla tifilole naa ti waye, tawon eeyan jade lopo yanturu lati ye obinrin naa si.
Gbogbo awon eeyan ti won ti gbo rekoodu tuntun yii ni won so pe awon orin olopolo,orin tawon musulumi gbodo maa gbo lo kun inu e bamubamu.
No comments:
Post a Comment