IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 10 September 2018

GOMINA AKINWUNMI AMBODE TI GBA FOOMU LATI DIJE GOMINA NINU EGBE APC

Gomina ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti gba foomu lati dije ipo gomina ninu egbe oselu egbe APC. 

Ile egbe naa to wa ni ACME Road, Agidingbi, lokunrin naa ti gba foomu yii niye towo re je milionu lona mejilelogun naira

No comments:

Post a Comment

Adbox