Ogunlogo awon eeyan ni won jona ku, topo farapa yannayanna ninu ijamba gaasi to gbina lagbegbe Lafia nipinle Nasarawa.
Lojiji la gbo pe ileese gaasi ohun gbana je, kawon eeyan too mo ohun to sele ina ti mu awon eeyan to wa lagbegbe yii, tokuu ti sun, topo eeyan si farapa.
Ki Olorun ba wa dawo aburu duro lorile-ede yii.
Monday, 10 September 2018
O MA SE O, BI OPO EEYAN SE JONA KU NINU IJAMBA INA TO SELE NI NASARAWA REE O
Tags
# ORO TO N LO
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
ORO TO N LO
Tags
ORO TO N LO
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment