IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 4 September 2018

Gbogbo omo Yoruba, a ku aseyinde Oba Ogunsua, tiluu Modakeke, to waja

Iroyin to te wa lowo ni Ojutole ni pe Oba Dr. Francis Olatunji Ologbin 1Adedoyin, Ogunsua tiluu   Modakeke ti waja. Oba Alade naa ti loo darapo mo awon baba nla e. Gbogbo omo Yoruba, a ku araferaku oba nla to lo.
Image may contain: one or more people

No comments:

Post a Comment

Adbox