Gbogbo eto lo ti pari ayeye ojoobi Arabirin Ejide ti yoo waye lojo kerinla osu yii ni 15000 Bellaire BLVD Suite X Houston TX 77083. Gbajugbaja olorin fuji taye n fe, Ambassado Akeem Adewale Alamu ni yoo forin aladun da awon eeyan lara ya lojo naa. Lasiko to n ba Ojutole soro, Alamu so pe gbogbo awon ololufe oun ni won yoo gbadun ara won daadaa pelu orin fuji to je eti ni gbese lojo naa.
Wednesday, 5 September 2018
Home
/
Unlabelled
/
GBAJUMO OLORIN FUJI NNI, AKEEM ADEWALE ALAMU NI YOO FORIN DABIRA NIBI AYEYE OJOOBI EJIDE
GBAJUMO OLORIN FUJI NNI, AKEEM ADEWALE ALAMU NI YOO FORIN DABIRA NIBI AYEYE OJOOBI EJIDE
Tags
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment