IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 4 September 2018

GBAJUGBAJA OLORIN TO FI AMERIKA SEBUGBE, YINKA RYTHMZ, GBE REKOODU MEJI JADE LEEKAN 'IFE MI ATI TELEPHONE CONVESARTION' LO PE E

Gbajugbaja olorin omo bibi orile-ede yii ni, sugbon to fi orile-ede Amerika, sebugbe ni, Yinka Rythmz ,  ti gbogbo aye mo si Omo Somebody, okunrin naa ti gbe rekoodu nla meji jade leekan naa.

Awo yii to pe akole re ni 'Ife mi atu Telephone Conversation' lawon eeyan fi n gbadun ara won kaakiri agbaaye bayii. Ninu rekoodu Ife mi lolorin to fi ilu Houston sebugbe, Chivibes ti kopa ninu e, bee ni Samson Ohda dari e.

Ni ti 'Telephone Conversation', okunrin kan ti won n pe ni Pappululu lo po o po. 

Fawon ti ko ba ranti mo, okan ninu awon omo agba-oje olorin fuji to doloogbe, Alaaji Rasheed Adio tawon eeyan tun mo si Mr.Somebody tabi Second Barrister l'Agerige ni Yinka. 

Yinka ni won fi joye Apase ilu West  Coast, bee lo tun je Atolase ilu Texas. Laipe yii lo gbe Dokita Ogonna Ifeayi niyawo lorile-ede Amerika.

Iwo naa le janfaani orin naa nipa kika a sile pelu linkii to wa nisale yii


 
DOWNLOAD IFE MI DOWNLOAD TELEPHONE LOVE

No comments:

Post a Comment

Adbox