IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 11 September 2018

GBAJUMO OLORIN EMI, EFANJELIISI ANYIN-O OWOEYE GBE REKOODU 'KING'S REWARD' JADE

Nile to mo loni-in, lara awon rekoodu awon olorin emin tawon eeyan, paapaa awon tile ologo je logun n gbo nile won bayii ni rekoodu 'King's Reward' 'Oba pinmileere' ti Efanjeliisi Ayin-O Owoeye sese gbe jade.

Rekoodu yii tileese Happy Shalom Production je alagbata e lawon orin emi to nitumo bii: Okan mi yin o, Open Heaven, King's Reward, Jehova Yeshua ati Big Miracle wa ninu e. Kaakiri ibi ti won ti n ta awon ojulowo rekoodu le o ti ri awo  yii ra.

Ileese Alpha P to wa ni Alapere ni won ti po orin yin po. Fun alaye lekunrere, e pe Anyi-O Owo

eye sori nomba yii:08028975859, 08031339710

No comments:

Post a Comment

Adbox