• GBAGEDE WA
  • NIPA WA
  • E KAN SI WA

IROYIN OJUTOLE

  • Home
  • OJUTOLE-TOKO
  • _NIPA WA
  • _IPOLOWO
  • IROYIN
  • LAGBO OSERE
  • ORO TO N LO
  • OSELU
  • ISELE KAYEEFI
  • FUN IPOLOWO +2348080597807

IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 5 September 2018

Home / OSELU / Mo kabaamo pe mo je ki ipinle Eko bo si egbe AD lowo lodun 2003- Abubakar Atiku

Mo kabaamo pe mo je ki ipinle Eko bo si egbe AD lowo lodun 2003- Abubakar Atiku

by IROYIN OJUTOLE on September 05, 2018 in OSELU

Awon agba bo, won ni eri okan se pataki, ohun teeyan ba n se, eri okan ni yoo maa je e kaakiri, irufe nnkan bee lo sele si igbakeji aare lorile-ede yii tele, Alaaji Atiku Abubakar, lojo Aje, Monde, ose yii, to fi toro aforiji lowo gbogbo omo egbe oselu PDP nipinle Eko pe ki won foriji oun lori asise toun se lati ma se je ki egbe naa wole nipinle naa lodun 2003.

O soro yii lakooko to n sabewo sawon omo egbe naa nipinle Eko, fun ti erongba e lati dije fun ipo aare labe egbe oselu naa ninu ibo to n bo lodun 2019. Gege bo se wi, o ni bo tile je pe aare orile-ede yii toun je igbakeji e, Oloye Olusegun Obasanjo pase foun pe koun ri i pe won gba gbogbo ile Yoruba fegbe oselu naa, sugbon toun kuna.

O ni nnkan to si fa a nigba naa ni ajosepo to danmoran to wa laarin oun ati Asiwaju Bola Ahmed Tinubu toun naa je gomina ipinle Eko lasiko naa. Gbogbo igba toun ba si n ro o, loun naa maa n kabamo pe asise nla loun se, o si je okan lara nnkan to mu ifaseyin  ba orile-ede yii, ti won ko fi kuro loju kan.
O so pe o se ni laaanu pe opo awon ti won je ki egbe PDP rowo mu nile Yoruba lodun 2003 ni won ti gba akoso egbe lowo won, ti ko si ye ko ri bee.O wa be awon omo egbe naa pe ki won foriji oun lori nnkan toun se yii ati pe iru e ko ni i sele mo.

Atiku  tun so siwaju si i pe nigba tawon gba ijoba  lodun 1999, gbogbo ile Yoruba lo je egbe oselu (Alliance for Democracy) lo n sakoso won. Nigba ti ibo mi in si n bo, oun so fun oga oun, iyen, Oloye Olusegun Obasanjo pe ko foun lase lati gba gbogbo ile Yoruba, o ni o si foun, Oun si se e ayafi ipinle Eko nikan ni ko bo sawon lowo nigba naa.

Idi to ni o fi ri bee ni pe oun ati Tinubu ti n bara won bo latinu egbe oselu SDP, PDM, nitori e loun se yonda Eko fun un nigba naa, bi ki i ba se bee ni o rorun foun lati gba Eko lowo e, amo ni bayii to ti je abamo foun nitori bi won tun ti se gba gbogbo ile Yoruba.

Okunrin naa wa so pe’ Mo be yin, ki e foriji mi, ki e si fun mi ni oore ofe mi.Ipinle Eko yoo sise papo pelu awon egbe oselu PDP yooku lati gbakoso’.

Leyin to ti se ipade po pelu awon agba ati oloye egbe naa tan ni ofiisi egbe naa, lo tun ba gbogbo awon omo egbe soro, nibi to ti toro fun iranlowo won lati satileyin fun un ki tikeeti lati dije naa lee te e lowo.
Lara awon to tele wa ni  Otunba Gbenga Daniel, to je oga agba isakoso iplongo fun Atiku ati Oloye Godsday Orubebe.

Tags # OSELU
Whatsapp
Author Image

Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.

Related Posts:
OSELU
By IROYIN OJUTOLE on - September 05, 2018
Email ThisBlogThis!Share to XShare to FacebookShare to Pinterest
Tags OSELU

No comments:

Post a Comment

Newer Post Older Post Home
Subscribe to: Post Comments (Atom)

KI LE N WA?

KARI AYE NI WON TI N KA A

Live Visitors Counter
Powered by Blogger.

AWON TO TI KA OJUTOLE-TOKO

Featured

E KAN SI WA 08080597807

Name

Email *

Message *

Most Popular

  • Yoruba lo yẹ ko jẹ aṣaaju nipa fila ati gele lagbaaye- Alake tilẹ Ẹgba
    Yoruba lo yẹ ko jẹ aṣaaju nipa fila ati gele lagbaaye- Alake tilẹ Ẹgba
    Alake tilẹ Ẹgba, Ọba Adedọtun Arẹmu Gbadebọ, ti ṣapejuwe Yoruba gẹgẹ bii aṣiwaju laarin awọn ẹya gbogbo kaakiri agbaye, paapaa, ...
  • Ó ṣẹlẹ,Arẹgbẹṣọla ati Gbadebọ Rhode-Vivour fẹẹ fi ẹgbẹ ADC gbajoba   Eko lọwọ   Tinubu ati APC
    Ó ṣẹlẹ,Arẹgbẹṣọla ati Gbadebọ Rhode-Vivour fẹẹ fi ẹgbẹ ADC gbajoba Eko lọwọ Tinubu ati APC
    Pẹlu bí  idibo ọdun  2027ṣe n sunmọ etile ẹgbẹ African Democratic Congress, ADC ti mura lati gba iṣakoso ipinlẹ Eko kuro lọwọ Aa...
  • Erongba wa ni lati ṣaaju awọn ọmọ orileede yii wọ ilẹ ileri lọdun 2027- Arẹgbẹṣola
    Erongba wa ni lati ṣaaju awọn ọmọ orileede yii wọ ilẹ ileri lọdun 2027- Arẹgbẹṣola
    Ọgbẹni  Rauf Arẹgbẹṣọla, akọwe fẹgbẹ ADC lapapọ ti sọ pe erongba wọn...
  • GNI pn ounjẹ fawọn alaawẹ ni wọn ba n fadura ranṣẹ si i
    GNI pn ounjẹ fawọn alaawẹ ni wọn ba n fadura ranṣẹ si i
    Titi di akoko ta a wa yii lawọn araalu fi adura ranṣẹ si Ọnarebu Gboyega Nasir Isiaka ti wọn tun pe ni GNI, to n ṣoju agbegbe Im...
  • Eyi lohun ti Iyayẹmi Ẹlẹbuibọn sọ nipa obinrin to n fi inu meji ba ọkọ lo
    Eyi lohun ti Iyayẹmi Ẹlẹbuibọn sọ nipa obinrin to n fi inu meji ba ọkọ lo
    Àràbà Awo ilẹ Oṣogbo. Araba Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn, ti ṣalaye ewu to wa fun iyawo ile ti ko jẹ oloootọ si ọkọ...
  •  Buhari lo fun Arẹgbẹṣọla nipo mìnìsita, ki i ṣe Tinubu- Amugbalẹgbẹ
    Buhari lo fun Arẹgbẹṣọla nipo mìnìsita, ki i ṣe Tinubu- Amugbalẹgbẹ
    Aṣiiri  ti  suyọ bayii pe Gomina tẹlẹ nipinlẹ Ọṣun, to tun figba kan jẹ minisita fọrọ abẹle, Ọgbẹní Rauf Arẹgbẹṣọla ki i ọmọọsẹ ...
  • Ìdẹ̀rún ọ̀tun yóò dé bá àwọn èèyàn ìjọ̀ba ìbílẹ̀ Ìdàgbàsókè Àpápá-Ìgànmú-Ọnarébù Ọlawálé Jímọ̀h
    Ìdẹ̀rún ọ̀tun yóò dé bá àwọn èèyàn ìjọ̀ba ìbílẹ̀ Ìdàgbàsókè Àpápá-Ìgànmú-Ọnarébù Ọlawálé Jímọ̀h
    Oludije fun ipo alaga nijọba ibile onidagbsoke Apapa-Iganmu,labẹ ẹgbẹ oṣelu APC, Ọnarebu Ọlawale Jimọh S...
  • Alaimọkan lo n sọ pe ayẹyẹ ọjọọbi Anọbi ko ṣe pataki- Al-Khaleefah Ọlọrunṣẹyẹ.
    Alaimọkan lo n sọ pe ayẹyẹ ọjọọbi Anọbi ko ṣe pataki- Al-Khaleefah Ọlọrunṣẹyẹ.
       Fadilat Sheikh Al-Khaleefah Abdul Quadri Ishọla Ọlọrunṣẹyẹ, to jẹ oludasilẹ ileewe JAMHYAT NUUR SOMODANY AL-ISLAMY FOUNDATION...
  • Tunde Lẹmọ ọna tooro to wọ Oke-Mọsan lọdun 2027
    Tunde Lẹmọ ọna tooro to wọ Oke-Mọsan lọdun 2027
    Bi ojumọ ṣe n mọ bẹẹ ni eto oṣelu fun ibo ọdun 2027, sunmọ etile tawọn araalu si ti n woye ẹni ti wọn yoo dibo wọn fun gẹgẹ bi a...
  • EGBE  BEBE AANU FUN ORIYOMI HAMZAT
    EGBE BEBE AANU FUN ORIYOMI HAMZAT
    Awon Omo egbe alatileyin fun gbajugbaja gbaja sorosoro  ori radio nni, Alhaji ORIYOMI Hamzat lati orile ede America ati Canada t...

Labels

  • BO SE N LO
  • IROYIN
  • KAYEEFI
  • LAGBO OSERE
  • ORO TO N LO
  • OSELU
Adbox

BO SE N LO

ipolowo oja

IROYIN TO GBAJUMO

Created By SoraTemplates | Distributed By Blogger Templates