IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 15 September 2018

ANKARA CUCCI, ODOMODE ALAWADA, TI DARAPO MO AWON OLOGUN OJU OFURUNFU






Iroyin ayo ree fun gbogbo awon ololufe odomode alawada ori ero ayelujara, Gafar Ahmed tawon eeyan mo si Ankara Cucci, omokunrin naa ti darapo mo awon omo ogun ofurunfu ti won n pe neefi.

Ileese awon ologun naa lomokunrin ti Olorun jogun imo nla fun yii ti n n se idanilekoo bayii.

No comments:

Post a Comment

Adbox