IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 1 September 2018

AJOKE CINDARELLA, OLORIN FUJI, SABEWO SI ALAAJI OLUOMO KUTONU, O NI EEYAN DAADAA LOKUNRIN NAA

Ojo nla lojo ti gbajumo osere fuji nni,Alaaja Fatimo Ajoke Cindarella, sabewo si ilu mo on ka aafaa nla, Sheik Alaaji Babatunde Saheed ti gbogbo aye mo si Oluomo Kutonu.

Ofiisi okunrin naa to wa niluu Eko ni Ajoke ti loo sabewo si i. Ninu osere fuji olopolo pipe yii lo ti sapejuwe Oluomo Kutonu gege bii eleyinju aanu eeyan to feran lat
i maa ran gbogbo awon eeyan lowo.  

No comments:

Post a Comment

Adbox