IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 29 August 2018

OLOHUN TOBI: AAFAA WO WERE SAN N'ILE-IFE

Ise iyanu Olorun sele laaro ijeta nigba ti aafaa onilawaani kan wo okunrin were olojo pipe kan san. 


Gege bi a se gbo, iwaju ile ijosin 'Catholic Church' to wa lagbegbe Lagere, niluu Ile-Ife, nipinle Osun, laafaa yii ti wo were ohun san. 

Leyin to gbadura fun un tan tara e ya, laafaa yii fi omi adura we were yii, bee ni won ge irun ori re, ti gbogbo awon eeyan to wa ni pe si n pariwo Alahu Akbar, Alahu Akbar.

Ninu oro aafaa yii lo ti so pe Olorun lo ran oun si okunrin were yii, o si parowa fun gbogbo awon eeyan to wa nibe pe ki won maa ran awon to ba ku die kaato fun lowo.

No comments:

Post a Comment

Adbox