IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 22 August 2018

NITORI ILEESE RADIO YINKA AYEFELE TIJOBA WO, SALAWA ABENI BINU SI AJIMOBI, NI GOMINA BA LAWON YOO RAN OKUNRIN NAA LOWO

Agba-oje olorin waka, Alaaja Salawatu Ibiwumi Abeni, ti fi ehonu e han lori bijoba ipinle Oyo se wo ileese 'Fresh FM' to je ti gbajugbaja olorin emi nni, Yinka Ayefele. Gentle Lady, bawon kan se n pe Salawa so pe ohun tijoba se yii, gbogbo awon osere pata lo kan, o si ye kawon jo dide soro naa ni

Osere   nla yii waa sadura fun Ayefele pe gbogbo ikolo re pata ni Olorun yoo da pada. Bakan naa la gbo pe Gomina Ajimobi ti so pe oun yoo saanu Ayefele lori ohun to sele yii, sugbon o buru jai bo se tapa sofi
n ipinle Oyo.

No comments:

Post a Comment

Adbox