IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 2 August 2018

Misturah Aderohunmu pe omo odun meeedogbon laye, e je ka ki aya Asafa ku oriire

Oni, ojo keji, osu kejo, odun 2018 ni gbajugbaja olorin Islam nni, Alaaja Misturah Aderohunmu Asafa ti gbogbo aye mo si Temi-ni-success pe eni odun meeedogbon laye.

Gbogbo awa osise ileese www.ojutole.com, iroyin ojutole-toko ati ojutole online tv la ki eeyan wa pataki ku oriire ojoobi re.

Adura gbogbo wa ni pe ki Amoke dagba, ko ju awon obi to bi i lo,ki Olorun jogun alaafia to peye, owo repete, emi gigun ati omo alalubarika fun un.


Igba odun,iseju aaya ni.

1 comment:

  1. Happy birthday long life and prosperity, May you live long like Olumo rock.. and may your history be eternal like that of AL-QURAN

    on behalf of: MORIKASU STUDENT ASS. OF NIG.

    Courtesy:NOHIBU AMIIR

    ReplyDelete

Adbox