Owo awon eso alaabo ti won n pe ni O- n-ya-bo ti te awon odomokunrin meji kan ti won feran lati maa wi okada gba moto lowo awon eeyan lagbegbe Ikorodu. Adugbo kan ti won n pe ni Agbede lowo ti ba awon eeyan naa lasiko ti won fee fibon gba okada lowo okunrin kan.
Awon eso alaabo to n sise niluu Ikorodu ni won ko fun awon eeyan naa laaye lati sise ibi won, ibinu lawon araalu fi ja awon sihooho, awon eso alaabo yii ko je kawon eeyan dana sun won.
Lojuese ni won fa won le awon agbofinro lowo.
Wednesday, 1 August 2018
Owo ti te won, awon adigunjale to fibon gba okada n'Ikorodu
Tags
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)


No comments:
Post a Comment