IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 27 August 2018

APPLE SPINNERS, OGA AWON OLORIN JUJU LO N SOJOOBI, E JE KA KI BABA DAADAA KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Iroyin Ojutole ati Ojutole Online Tv la ki eeyan wa daadaa, Alagba Apple Spinners ku oriire ojoobi won to waye loni-in. Adura wa si won ni pe ki baba daadaa sopo odun laye ninu owo, ola, ati alaafia to peye.

Lagbara Olorun e o ni i mo saare omo, idaamu aye ko ni i je ti yin. Igba odun,iseju aaya ni sa.
   

No comments:

Post a Comment

Adbox