IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 11 January 2025

EGBE BEBE AANU FUN ORIYOMI HAMZAT


Awon Omo egbe alatileyin fun gbajugbaja gbaja sorosoro 
ori radio nni, Alhaji ORIYOMI Hamzat lati orile ede America ati Canada toro itusile fun okunrin eleyinju aanu naa lori laasigbo to sele niluu Ibadan nibi ti ajo kan ti fee pin ebun odun fun awon araalu.


Ninu atejade ti awon adari egbe yii, Arabinrin Toyosi Oladipo ati Arabinrin Rashidat Aina fowo si, won ba awon obi ati ebi awon to ku ninu laasigbo naa kedun.
Won salaye pe eleyinju aanu ni Alhaji ORIYOMI Hamzat. Ko le dara fun ara ilu lo nba kiri.


 Olugbeja mekunnu ati awon ti won ba n yanje ni gbogbo aye mo si.
Awon egbe yi gboriyin fun atileyin awon ara ilu lori oro yi. Bee naa ni won ni awon o lodi si iwadii ti awon agbofinro n se lori isele  naa.


 Sugbon, won fe ki won gba beeli okunrin eleyinju aanu yii ati awon yoku to wa latimole.
Oore ni awon ajo to gbe eto naa kale fee se, to wa fee di ibi bayi. Alhaji Hamzat kan ba won polongo eto naa ni.


wo ebe fun itu sile Alhaji Oriyomi Hamzat lai fi akoko sofo lori oro naa.

No comments:

Post a Comment

Adbox