Nitori ipa nla ti okunrin naa n ko fun idagbasoke ati ilosiwaju esin islam ni won tori e fun un loye nla yii. Bamubamu lawon eeyan pataki lawujo kun ibi ti ayeye yii ti waye. Gbogbo wa nileese Ojutole naa ki baba oloye tuntun pe won yoo remi-in ati alaafia lo o.
Ojo Aiku, Sannde anaa, nijo alasalatu kan toruko re n je 'Al-Mustapha' fi gbajugbaja onisowo, to tun je oga-agba ileese to n ba ni seto irin-ajo lo soke okun, 'Al-Hatyq Travel and Tours Limited', iyen Otunba Mutiu Badmus Adewale joye Sanmori Adinni ijo naa.
Nitori ipa nla ti okunrin naa n ko fun idagbasoke ati ilosiwaju esin islam ni won tori e fun un loye nla yii. Bamubamu lawon eeyan pataki lawujo kun ibi ti ayeye yii ti waye. Gbogbo wa nileese Ojutole naa ki baba oloye tuntun pe won yoo remi-in ati alaafia lo o.
Nitori ipa nla ti okunrin naa n ko fun idagbasoke ati ilosiwaju esin islam ni won tori e fun un loye nla yii. Bamubamu lawon eeyan pataki lawujo kun ibi ti ayeye yii ti waye. Gbogbo wa nileese Ojutole naa ki baba oloye tuntun pe won yoo remi-in ati alaafia lo o.
No comments:
Post a Comment