IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 18 March 2019

WASIU AYINDE SABEWO SAWON TORI KO YO NINU IJAMBA ILE TO WO NI ITAFAJI

Gbajumo osere fuji nni, Alaaji Wasiu Ayinde Omogbolahan naa ti darapo mo awon eeyan pataki ti won loo sabewo sawon eeyan ti ori ko yo ninu ijamba ile to wo lose to koja ni Itafaji, nigboro Eko.

Lasiko to ba n wa awon omode atawon agba ti Olorun ko yo yii dupe lowo Olorun, osere nla yii so pe gege bii eni to dide lati adugbo yii, o pon dandan koun kedun pelu awon eeyan oun yii. 

Bee lo gbadura pe Olorun yoo tu awon to padanu eeyan won sinu ijamba naa

ninu. Osere nla yii waa gbadura fawon to n gbatoju pe layo ati alaafia ni won yoo pada sile won.

No comments:

Post a Comment

Adbox