IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday 22 March 2019

O TAN: ILEEJO TIRABUNA NI ADELEKE TEGBE PDP LAWON ARA OSUN DIBO GOMINA FUN, SUGBON OYETOLA SO PE ILEEJO GIGA LAWON YOO TI YANJU E

    Igbimo  to n gbo awon magomago to jeyo lasiko idibo gomina ipinle Osun ti so pe oludije ninu egbe oselu PDP, Senato Ademola Adeleke lawon ara ipinle Osun dibo yan ninu eto idibo to waye ninu osu kesan-an odun to koja, ohun ti ileejo yii so ni pe ibo ti Adeleke ni ju ti Gboyega lo. 
    Igbimo eleni meta yii ti Alagba Ibrahim Sirajo saaju won lo ti pa ajo to n seto ibo lase lati fun Adeleke niwe eri gege bii ojulowo gomina ipinle Osun.   
    Igbimo yii so pe osise ajo INEC, ko lagbara lati seto atundi ibo gege bo se waye nipinle Osun ati pe atundi ibo to gbe Gboyega Isiaka wole yii ko ba ofin mu. 
     
    Sugbon, egbe APC ati Gboyega Isiaka ti gba ileejo giga lo, won lawon ko faramo ejo tigbimo tirabuna yii da. Nibi tor

    o de bayii, idajo ileejo giga lawon eeyan n duro de bayii.

No comments:

Post a Comment

Adbox