IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday 23 March 2019

NNKAN DE O: ENIOLA BADMUS,OSERE TIATA YORUBA LOUN YOO PA ARA OUN

Olorun lo mo iru adanwo to sele si okan ninu awon gbajumo osere tiata Yoruba wa, Eniola Badmus, tawon eeyan tun mo si Gbogbo Biz Girls, ti osere naa fi so pe oun yoo pa ara oun danu.

Ori eka ayelujara ti won n pe ni 'Twitter' ni Eniola gbe e si i pe boya loun ko ni i pa ara oun bayii, o ni ohun ti oun ro lowolowo niyen.

Gbogbo awon eeyan ti won ri ohun to so yii lo se ni kayeefi nla, ibeere kan ti gbogbo n beere ni pe iru adanwo wo lo de ba  osere yii to fi  ro pe iku lo to si oun.

No comments:

Post a Comment

Adbox