IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday 23 March 2019

ONI LOJOOBI ARABIAN JERRY, GBAJUGBAJA OLORIN JUJU, E JE KA KI OGBENI BRABRA KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, Omooba Arabian Jerry, ku ayeye ojoobi e to waye loni-in. 

Adura wa ni pe ki omo Badejo sopo odun laye ninu owo, ola, igbega ati alubarika repete. Igba odun, iseju aaya ni fun Ogbeni Brabra to kari aye.

No comments:

Post a Comment

Adbox