IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday 23 March 2019

AWA ONIMOTO KI I SE OMOOTA, A KO YATO SI LOYA TABI ENJINNIA, MC OLUOMO LO SO BEE O

Akapo egbe awon onimoto nipinle Eko, Alaaji Musiliu Ayinde ti gbogbo aye mo si MC Oluomo ti so pe awon omo egbe onimoto NURTW ki i se omoota, gege bawon eeyan se maa n so. 

Okunrin yii ti won tun n pe ni Ayedaade te siwaju ninu oro e pe awon ko
yato sawon akosemose ti won gba iwe eri nileewe bii looya tabi enjinnia, kawon araalu ma foju toogi wo awon mo.

Lori eka ayelujara ti won tun n pe ni twitter ni MC Oluomo ju oro yii si.

No comments:

Post a Comment

Adbox