Lasiko toun ati igbakeji e, Alaaja Jemilat Alagbe, sabewo si Akinlade lo ti so fun gbogbo awon alatileyin e pe Akinlade ni won ki won dibo fun lojo Abameta,Satide to n bo yii.
Bi ojo ibo gomina se ku si ojo meji, oludije ipo gomina labe oselu PDP, Onarebu Oladipupo Adebutu ti juwo sile fun oludije gomina legbe oselu APM, Onarebu Adekunle Akinlade.
Lasiko toun ati igbakeji e, Alaaja Jemilat Alagbe, sabewo si Akinlade lo ti so fun gbogbo awon alatileyin e pe Akinlade ni won ki won dibo fun lojo Abameta,Satide to n bo yii.
Lasiko toun ati igbakeji e, Alaaja Jemilat Alagbe, sabewo si Akinlade lo ti so fun gbogbo awon alatileyin e pe Akinlade ni won ki won dibo fun lojo Abameta,Satide to n bo yii.

No comments:
Post a Comment