Bi eto idibo lati yan gomina se ku ojo kan soso, gbajugbaja osere fuji nni, Alaaji Sulaimon Adio Atawewe, ti gbogbo aye mo si Etu Fuji ti so pe oludije labe egbe oselu APC nipinle Eko, Ogbeni Babajide Sanwo-Olu ni kawon ara Eko dibo won fun.Atawewe, tawon mi-in tun mo si Baba Oloye soro yii nibi ayeye ojoobi tawon ololufe e se fun un nile igbafe 'Vegas' to wa ni Opebi.
Ilu mo on kan osere fuji ni ki ilosiwaju ati idagbasoke otun le e de ba ipinle Eko,Sanwo-Olu ni kawon ara Eko fibo gbe wole lati te e siwaju nibi ti Ambode ba a de.
Osere nla yii waa ro gbogbo awon odo lati yago fun iwa jandunku tabi jagidijagan lasiko ibo naa.

No comments:
Post a Comment