IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday 10 March 2019

AWON JANDUKU OLOSELU YINBON FUN TAYE CURRENCY ATI MAMA E 'IBADAN

Iroyin to te Ojutole lowo bayii ni pe awon jandunku oloselu kan ti yinbon fun gbajumo osere fuji nni, Alaaji Taye Adebisi Currency ati mama e. Ile won to wa lagbegbe Apata, niluu Ibadan ni won ka won mo. Ileewosan lawon mejeeji wa bayii ti won ti n gba itoju.

Aaro oni yii kan naa ni won yinbon pa iyawo Auxilliary oga awon onimoto tele nipinle Oyo, ibe naa ni won tun ti yinbon fun Onarebu Temitope Sugar.

Ohun

ti a gbo bayii ni pe ilu Ibadan ko fararo rara lasiko yii. 

No comments:

Post a Comment

Adbox