IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday 10 March 2019

Yussuf, omo Taye Currency onifuji wole sipo asofin nipinle Oyo

Yusuff Oladeni Adebisi, akobi gbajumo osere fuji nni,Taye Adebisi Currency, lawon ara ekun idibo Iwo-Oorun ilu Ibadan dibo fun gege bii asofin ti yoo soju won nile igbimo asofin ipinle Oyo fun odun merin.

Inu egbe oselu PDP lomokunrin naa ti gbapoti ibo to fi wole yii. O

jutole gbo pe faaji nla ti sele nile awon Taye Currency pelu oriire ti omo re se yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox