IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 8 January 2019

OSU KERIN ODUN YII LASEKAGBA AYEYE OKU BABA OBA ARA, OLOYE BABAJIMI ONIMOLE, YOO WAYE

Ki i se ohun tuntun tabi ohun ti eti ko gbo ri pe gbajugbaja olorin emi nni, Efanjeliisi Dokita Onimole Rotimi Okikiola ti gbogbo aye mo si Oba Ara ti padanu baba e, Oloye CPL Babajimi Joseph Onimole, ti won ti sin in lojo keji, osu kin in ni, odun yii, ti i  se ojo ojoobi e gangan. Sugbon iroyin to te Ojutole lowo bayii ni pe awon ebi osere nla yii ti mu ojo ketadinlogbon, osu kerin, odun yii gege bii ojo ti won yoo se asekagba ayeye oku baba soja to lo yii.

A gbo pe ipade ti  n lo lowo laarin Oba Ara pelu awon ebi e lori bayeye naa yoo se larinrin, ti gbogbo aye yoo mo pe awon omo alalubarika ni baba yii fi saye lo

.

No comments:

Post a Comment

Adbox