IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 7 January 2019

GONGO SO LOJO TI SHEIK JAMIU AMIN-OLOHUN GBE HAJIA BALIKS NIYAWO L'AMERIKA

Titi dasiko yii lawon ara ilu Texas, lorile-ede Amerika si n soro nipa ayeye igbeyawo gbajugbaja aafaa oniwaasi nni, Sheik Jamiu Ajadi Sanusi Amin-Olohun to waye lanaa, ojo Aiku, Sannde. Ojo naa ni ojogbon sheik  yii gbe Hajia Balikis niyawo.








Gbogbo awon ara adugbo yii ni won mo pe eeyan nla lo se nnkan nla lojo naa, bamubamu nibi ti won lo fun ayeye yii kun awon eeyan pataki lawujo.

Lasiko to n ba Ojutole soro, Sheik Amin-Olohun dupe lowo awon eeyan ti won fi ojo naa ye e si, o sapejuwe iyawo e bii ebun pataki ti Olorun fi ta oun lore. 

No comments:

Post a Comment

Adbox