IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 8 January 2019

IYA-N-Ghana, GBAJUGBAJA OLORIN ISLAM LO SOJOOBI, GBOGBO AYE LO KI I KU ORIIRE

Oni ni ilu mo on ka akorin esin Islam nni, Queen Seidat Dokita Bashirat Ogunremi Olomitutu ti gbogbo aye mo si Iya-n-Ghana n sayeye ojoobi e , gbogbo aye pata ni won ba arewa akorin-gbesin-ga yii sayeye ojoobi naa.

Awa naa nileese Ojutole ba eeyan wa pataki yii dupe lowo Olorun fun ojo oni-in, adura wa ni pe ki Iya-n-Ghana  sopo odun
laye ninu ola, owo,alaafia ati alubarika to po jaburata. Igba odun, iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox