Inu idunnu ati ayo lawon ebi gbajumo olorin Islam nni, Hajia Sofiyat Abdulkareem tawon eeyan mo si Iya-n-Kaola wa bayii, obinrin naa sese bimo obinrin sorile-ede Amerika.
Ilu Dallax la gbo pe osere naa bimo si, layo ati alaafia la gbo pe iya atomo tuntun wa. Olorun yoo wo omo naa yoo da a si i
.
Saturday 8 December 2018
OPE O: IYA-N-KAOLA OLORIN ISLAM BIMO OBINRIN S'AMERIKA
Tags
# LAGBO OSERE
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
LAGBO OSERE
Tags
LAGBO OSERE
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment