IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday 1 December 2018

ONI LOJOOBI OLOYE TOKUNBO BABS OLURINDE, E JE KA KI SKIN DUDU KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki egbon wa daadaa, egbon wa pataki, Oloye Otunba Tokunbo Babs Olurinde ti gbogbo aye mo si Skin Dudu ku oriire ayeye ojoobi won.

Inu wa dun, ara wa ya pe ojo oni soju gbogbo wa, adura wa ni pe ki e sopo odun laye ninu ola,owo,alaafia ara ati arisiki nla. 

Igba odun, iseju aaya ni fun oga awon pede
pede l'Ekoo  

No comments:

Post a Comment

Adbox