Leyin to san gbogbo eto ati owo beeli tile-ejo giga to fi kale siluu Eko so pe ko san lori esun tajo EFCC fi kan an, gomina ipinle Ekiti tele, Ogbeni Ayodele Fayose ti pada sile e, okunrin naa ti bo lowo ajo EFCC bayii.
Osan yii ni Fayose atawon eeyan e pada sile, leyin to ti san owo atawon nnkan mi-in tile-ejo ni ko san gege bii owo beeli esun ti won fi kan an yii

No comments:
Post a Comment