
Ojo Fraide to koja yii lawon eeyan kan ti won pe ni hayakila yinbon fun okunrin naa niluu Akure, ori la gbo pe won ti yinbon fun un, ti won si sare gbe e lo sile iwosan ijoba nibi to pada dake si.
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
No comments:
Post a Comment