Gbogbo eto lo ti pari lori ayeye onibeta ti gbajumo olorin musulumi nni, Hajia Shukurat Wazzi tawon eeyan mo si Akobi-Ayeloyun fee se. Ayeye ohun ni ifilole rekoodu tuntun, ifilole ajo 'Akobi-Ayeloyun Music International' ati sise eye nla fun gbajugbaja olorin Islam nni, Alaaja Bashirat Ogunremi ti gbogbo aye mo si Iya-n-Ghana.Ojo kerindinlogun,osu kejila, odun yii layeye nla ohun yoo waye.
IYA-N-GHANA |
Gbongan 'Amje Event Centre' to wa ni Amje Bustoopu, oju-ona marose Eko s'Abeokuta layeye naa yoo ti waye. Bakan naa ni Ojutole gbo pe won yoo tun fun awon eeyan pataki kan lawujo lami-eye lojo naa.
Aso kampala elegberun merin naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye nla yii.
No comments:
Post a Comment