IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 22 September 2018

ONI LOJOOBI IYA ORIKI, E JE KA KI OJULOWO OMO YORUBA YII KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese OJUTOLE la ki eeyan wa daadaa, ojulowo omo Yoruba, ogbontarigi agbasaga, Arabinrin Ayo Ewebiyi ti gbogbo aye mo si Iya Oriki ku oriire ayeye ojoobi e.

Adura wa ni pe komo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo, arisiiki repete ati alaafia ara to peye. E ti sodun eleyii naa, e o semi-in tayotayo lola Eledaa. Igba odun, iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox