IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 19 September 2018

OJO FRAIDE TO N BO YII LAYEYE IFILOLE 'EGBE KABIIESI OWURO LA WA FANS CLUB' YOO WAYE

Ojo Eti, Fraide, to n bo yii layeye ifilole awon ololufe agba-oje ati gbajugbaja sorosoro ori radio ati telifisan, Oloye Abdulkabir Adeyinka Adewoye ti gbogbo aye mo si Kabieesi Owuro la wa yoo waye. 

Ile igbafe 'Vertical Hotel and Suite' to wa niluu Igbogbo, nipinle Eko layeye naa yoo ti waye. Ilu mo on ka osere fuji nni, Alaaji Sule Alao Adekunle Malaika ni yoo saaju awon olorin ti won yoo forin aladun dabira lojo naa.


No comments:

Post a Comment

Adbox