.Iroyin ibanuje to te wa lowo ni pe odomode olorin Islam nni, Aishat Ayopo ti padanu baba e, Ogbeni , Akintunde Ayopo.
Titi dasiko yii niku okunrin naa ti won pe ni osere tiata Yoruba nipinle Ogun si n se awon ni kayeefi nla, nitori pe okunrin ti won pe lomo egbe TAMPAN naa ko saisan rara.
Ki Olorun fori ji i, ko duro ti awon to fi sile.
No comments:
Post a Comment