IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 10 September 2018

EYIN ARA SURULERE, E JE KA FIBO GBE ONAREBU DEJI AWOBOTU WOLE, GEGE BII ASOFIN NILE- IGBIMO ASOFIN EKO

Asiko ti to ki gbogbo awon omo egbe oselu APC lekun idibo Surulere  keji fibo gbe Onarebu Dokita Deji Awobotu(FCA) wole ninu ibo abele egbe naa to n bo lona gege bii asofin wa ti yoo soju wa nile igbimo asofin ipinle Eko.

E je ka dibo fun eni to nifee awon araalu denudenu, eni ti yoo soju wa daadaa ti mudunmudun ijoba awarawa yoo  fi to gbogbo wa lowo.

 E je ka dibo fun olopolo pipe, onimo nla, omoluabi to mo ibi ti bata ti n ta wa lese.E je ka dibo fun eni tojo iwaju wa ati tawon omo wa je logun. E ma gbagbe o, Deji Awobotu ni ka fibo wa gbe wole lojo ibo abele yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox