IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 9 September 2018

TUNDE DAMENDRA, GBAJUMO OSERE FUJI, FEE SAYEYE OJOOBI AADOTA ODUN, O TUN FEE KO IRINSE TUNTUN JADE

Gongo yoo so lojo ketalelogun, osu kewaa, odun yii, ojo naa ni gbajumo osere fuji to fi ilu Eko sebugbe, Mayor Tunde

Damenra, yoo sayeye ojoobi aadota odun. Bakan naa losere tawon eeyan feran daadaa yii yoo tun ko irinse orin olowo nla jade.
Gbongan Badewa House to wa ni No 42 Elebiju,  Demurin, ni Alapere, nipinle Eko layeye nla ohun yoo ti waye. 

Lara awon osere  fuji ti won n reti nibi ayeye yii ni: Alaaji General Kolligton Ayinla, Alaaji Abass Akande Obesere, Adewale Ayuba, Sir Shina Akaani, Alaaji Rasheed Ayinde, Alaaji Sule Alao Malaika,Alaaji Musiliu Haruna Ishola, Ishola Sandoka, Lokoso Ajani, Fatai Valentine atawon mi-in. 
Ankara egberun merin naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye yii.

Fun alaye lekunrere, e pe Damendra sori nomba yii:08098739168

No comments:

Post a Comment

Adbox