IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 9 September 2018

AWON EEYAN BA ALFA-MI-NI SAJOYO ABODE MEKA

Pelu ayo ati idunnu lawon eeyan fi ba Khalifa Ismael Aderemi Alfa-mi-ni sajoyo ile Oluwa,iyen Meka to lo lodun yii. 

Se lawon eeyan jade logun-logbon lati ba aafaa oniwaasi, to tun n korin yii dupe lowo Olorun pe o lo si Meka layo, bee lo de layo.

Awa naa ba baba daadaa, oninuure dupe lowo Olorun,adura wa ni pe e o ni i fade Meka toro je laelae


No comments:

Post a Comment

Adbox