IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 2 August 2018

E wo, Alaaji Olumo Kutonu, okan ninu awon asaaju omo Yoruba nile okere

Enikeni to ba de ilu Kutonu, iru eni bee ko ni i rin jina ti yoo fi mo pe okan ninu awon omo Yoruba ti won n gbe oruko orile-ede yii ga nibe ni Alaaji Babatunde Saheed  Yusuff, ti gbogbo aye mo si Oluomo Kutonu.

Ipo nla laafaa naa di mu ninu awon asaaju Yoruba ni Kutonu, iyen nikan ko, akole kan wa ti won gbe si oju ona atiwo ilu Kutonu, foto ati oruko Oluomo lo wa nibe, ohun ti won ko sibe niyii 'Oluomo Arena'. Akole yii lo salaye beeyan yoo se de ile Oluomo Kutonu.

Enikeni to ba wa ri, Alaaji Saheed, e so fun un pe awa mo riri re, okan pataki ninu aw

on omo orile-ede yii ni. 

No comments:

Post a Comment

Adbox