IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 3 August 2018

ALAAJA ASABI OLAOMOPO LO N SOJOOBI, E JE KA KI I KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese www.ojutole, Iroyin Ojutole-Toko ati Ojutole Online TV la ba eeyan wa daadaa, eeyan wa oloriire, Alaaja Taibat Asabi Olaomopo la ki i ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in ojo keta, osu kejo, odun 2018.

Inu wa dun pe ojo oni soju gbogbo wa, adura wa ni pe ki Ashabi sa pounds se opo odun laye, ki Mama Fathia, Mama Al-Amin sopo odun laye ninu ola, owo, oro ati alubarika nla.

Ke e pe, ke e gbo, ke e dagbadagba pelu ohun meremere, lagbara Olorun e o ni i mo saare omo. Hapi batide, Alashabi ti wa.

No comments:

Post a Comment

Adbox