IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 19 March 2024

Gbajumo aafaa, Alhaji Saheed Oluomo Cotonou fi ounjẹ toore fawon musulimi


Bi awon musulumi kaakiri agbaaye se n gbawee Ramadan, gbajugbaja aafaa onisegun, Alhaji Dokita Muhammad Saheed Babatunde ti gbogbo aye mo si Oluomo Cotonou ti fi ounjẹ ofe toore fawon musulimi to ku die kaato fun.

Gege bi a se gbo, orisirisii ounjẹ la gbo pe aafaa nla Omo bibi ilu Ilorin naa Fi ta ogunlogo awon eeyan lore. Ninu oro e, Oluomo Cotonou ni asiko ise ladaa ati ise oloore la wa yii, gbogbo wa la si mo ohun to n sele kaakiri agbaaye, nitori ni mo se wo o pe ki n fun awon eeyan lounje. Lara ohun ti mo feran ju laye ni oore sise, o si je ohun ti Olorun nifee si.

No comments:

Post a Comment

Adbox